Nuacht

Wọ́n ní ọkùnrin náà, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ugochukwu àmọ́ tí wọ́n máa ń pè é ní Ude Papa, jẹ́ ẹni tó máa ṣe bàtà ní ọjà Ariaria ...
Nínú fídíò kan tó gba orí ayélujára, ẹnìkan, tí ìgbàgbọ́ wà pé ó jẹ́ ọmọlẹ́yìn Paso ń sọ pé àwọn kan ṣe ìkọlù sáwọn ní Ikire.